Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 30:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi wà pẹ̀lú rẹ, n ó sì gbà ọ́,’ni Olúwa wí.‘Bí mo tilẹ̀ pa gbogbo orílẹ̀ èdè run,nínú èyí tí mo ti fọ́n ọn yín ká,síbẹ̀ èmi kì yóò pa yín run pátapáta.Èmi yóò bá yín wí pẹ̀lú ìdájọ́ òdodo nìkan;Èmi kò ní fi yín sílẹ̀ láìjìyà.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:11 ni o tọ