Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 30:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nítorí náà, má ṣe bẹ̀rù, Ìwọ Jákọ́bù ìránṣẹ́ mi,má sì ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, Ìwọ Ísírẹ́lì,’ni Olúwa wí.‘Èmi yóò gbà ọ́ kúrò láti ọ̀nà jínjìn wá,àní àwọn ìran rẹ láti ilẹ̀ àtìpó wọn.Jákọ́bù yóò sì tún ní àlàáfíà àti ààbò rẹ̀ padà,kò sì sí ẹni tí yóò ṣẹ̀rù bà á mọ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 30

Wo Jeremáyà 30:10 ni o tọ