Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 29:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ti rán iṣẹ́ yìí sí wa ni Bábílónì wí pé, àtìpó náà yóò pẹ́ kí ó tó parí, nítorí náà, ẹ kọ́ ilé kí ẹ sì máa gbé ibẹ̀, ẹ dá oko, kí ẹ sì máa jẹ èṣo ohun ọ̀gbìn oko yín.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 29

Wo Jeremáyà 29:28 ni o tọ