Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 29:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa Ọlọ́run alágbára wí pé: “Èmi yóò rán idà, ìyàn àti àjàkálẹ̀-àrùn sí wọn; Èmi yóò sọ wọ́n dà bí ọ̀pọ̀tọ́ búburú tí kò ṣe é jẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 29

Wo Jeremáyà 29:17 ni o tọ