Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 29:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Olúwa wí: “Nígbà tí ẹ bá lo àádọ́rin ọdún pé ní Bábílónì, èmi yóò tọ̀ yín wá láti ṣe àmúṣẹ ìlérí ńlá mi fún un yín, àní láti kó o yín padà sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin Jeremáyà 29

Wo Jeremáyà 29:10 ni o tọ