Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 27:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Èmi kò rán wọn ni Olúwa wí. Wọ́n ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké ní orúkọ mi. Nítorí náà, Èmi yóò lé wọn, wọn yóò sì ṣègbé, ẹ̀yin pẹ̀lú àwọn wòlíì tí ó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún un yín.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 27

Wo Jeremáyà 27:15 ni o tọ