Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 27:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe fetí sílẹ̀ sí ọ̀rọ̀ àwọn wòlíì tí ó ń sọ wí pé, ‘Ẹ̀yin kò ní sin Ọba Bábílónì,’ nítorí pé àsọtẹ́lẹ̀ eké ni wọ́n ń sọ fún un yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 27

Wo Jeremáyà 27:14 ni o tọ