Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 26:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì mú Úráyà láti Éjíbítì lọ sí ọ̀dọ̀ Ọba Jéhóíákímù; ẹni tí ó fi idà pa, ó sì sọ òkú rẹ̀ sí inú isà òkú àwọn ènìyàn lásán.)

Ka pipe ipin Jeremáyà 26

Wo Jeremáyà 26:23 ni o tọ