Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 26:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Míkà ti Mórásì sọ àsọtẹ́lẹ̀ ní ọjọ́ Heṣekáyà Ọba Júdà. Ó sọ fún gbogbo ènìyàn Júdà pé, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“ ‘A ó sì fa Síónì tu bí okoJérúsálẹ́mù yóò di òkítìàlàpà àti òkè ilẹ̀ yìí gẹ́gẹ́ bíibi gíga igbó.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 26

Wo Jeremáyà 26:18 ni o tọ