Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 23:39-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

39. Nítorí náà, Èmi yóò gbàgbé yín, bẹ́ẹ̀ ni n ó lé e yín kúrò níwájú mi pẹ̀lú àwọn orílẹ̀ èdè tí mo fi fún un yín àti àwọn baba yín.

40. Èmi yóò sì mú ìtìjú ayérayé wá sí orí yín, ìtìjú tí kò ní ní ìgbàgbé.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 23