Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 23:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, Èmi yóò gbàgbé yín, bẹ́ẹ̀ ni n ó lé e yín kúrò níwájú mi pẹ̀lú àwọn orílẹ̀ èdè tí mo fi fún un yín àti àwọn baba yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 23

Wo Jeremáyà 23:39 ni o tọ