Jeremáyà 20:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Ṣùgbọ́n Olúwa wà pẹ̀lú mi gẹ́gẹ́ bí jagunjagun alágbára.Nítorí náà, àwọn tí ó ń lépa mi yóò kọsẹ̀,wọn kì yóò sì borí.Wọn yóò kùnà, wọn yóò sì gba ìtìjú púpọ̀.Àbùkù wọn kì yóò sì di ohun ìgbàgbé.