Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 19:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì wí pé ‘Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa ẹ̀yin Ọba àwọn Júdà àti ẹ̀yin ará Jérúsálẹ́mù. Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ. Dẹtí sí mi! Èmi yóò mú ìparun wá síbí, etí gbogbo wọn tó bá gbọ́ ọ yóò hó yaya.

Ka pipe ipin Jeremáyà 19

Wo Jeremáyà 19:3 ni o tọ