Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 19:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun wí. Èmi a fọ́ orílẹ̀ èdè yìí àti ìlú yìí gẹ́gẹ́ bí ìkòkò amọ̀ yìí ṣe fọ́ tí kò sì ní sí àtúnṣe. Wọn a sì sin àwọn òkú sí Tófẹ́tì títí tí kò fi ní sí àyè mọ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 19

Wo Jeremáyà 19:11 ni o tọ