Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 18:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síbẹ̀ ni àwọn ènìyàn mi ti gbàgbé mi,wọ́n sun tùràrí fún òrìṣà aṣántí ó mú wọn kọsẹ̀ ní ọ̀nà wọn àti ọ̀nà wọn àtijọ́.Wọ́n mú wọn rìn ní ọ̀nà àtijọ́ àti ní ojú tí a kò kọ́

Ka pipe ipin Jeremáyà 18

Wo Jeremáyà 18:15 ni o tọ