Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò dàbí igi tí a gbìn sí ipadòtí ó ta gbòǹgbò rẹ̀ ká etí odòkò sí ìbẹ̀rù fún-un nígbà ooru,gbogbo ìgbà ni èwe rẹ̀ máa ń tutùkò sí ìjáyà fún-un ní ọdún ọ̀dábẹ́ẹ̀ ni kò ní dẹ́kun láti máa so èso.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 17

Wo Jeremáyà 17:8 ni o tọ