Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 17:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe gbé ẹrù jáde kúrò nínú ilé yín, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má ṣe ṣe isẹ́kísẹ́ ní ọjọ́ ìsinmi ṣùgbọ́n kí ẹ pa ọjọ́ ìsinmi mọ́ fún àwọn baba ńlá yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 17

Wo Jeremáyà 17:22 ni o tọ