Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi fi ọ́ ṣe odi idẹ tí ó lágbárasí àwọn ènìyàn wọ̀nyí. Wọn ó bá ọ jàṣùgbọ́n, wọn kò ní lè borí rẹnítorí pé, mo wà pẹ̀lú rẹ láti gbà ọ́ là,kí n sì dáàbò bò ọ́,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 15

Wo Jeremáyà 15:20 ni o tọ