Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 15:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà báyìí ni Olúwa wí:“Tí o bá ronúpìwàdà, Èmi ó dá ọ padàwá kí o lè máa sìn mí. Tí ó básọ ọ̀rọ̀ tó dára ìwọ yóò di ọ̀gbẹnusọmi. Jẹ́ kí àwọn ènìyàn yìí kọjú sí ọ;ṣùgbọ́n ìwọ kò gbọdọ̀ kọjú sí wọn

Ka pipe ipin Jeremáyà 15

Wo Jeremáyà 15:19 ni o tọ