Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 14:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ èyíkéyìí àwọn òrìṣà yẹ̀yẹ́ tí àwọn orílẹ̀ èdè le ṣe kí òjò rọ̀?Ǹjẹ́ àwọ̀sánmọ̀ fúnra rẹ̀ rọ òjò bí?Rárá, ìwọ ni, Olúwa Ọlọ́run wa.Torí náà, ìrètí wa wà lọ́dọ̀ rẹ,nítorí pé ìwọ lo ń ṣe gbogbo nǹkan wọ̀nyí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 14

Wo Jeremáyà 14:22 ni o tọ