Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 12:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àlìkámà ni wọn yóò gbìn, ṣùgbọ́n ẹ̀gún ni wọn yóò ká,wọn yóò fi ara wọn ṣe wàhálà, ṣùgbọ́n òfo ni èrè wọn.Kí ojú kí ó tìyín nítorí èrè yín,nítorí ìbínú gbígbóná Olúwa.

Ka pipe ipin Jeremáyà 12

Wo Jeremáyà 12:13 ni o tọ