Gbogbo ibi gíga tí ó wà nínú aṣálẹ̀ni àwọn apanirun ti gorí,nítorí idà Olúwa yóò paláti ìkángun kìn-ín-ní dé ìkángun ìkejì ilẹ̀ náà;kò sí ẹni tí yóò yè.