Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sílífà tí a ti kàn ni a mú wá látiTásísì, àti wúrà láti Lépásì; èyí tíàwọn onísọ́nà àti alágbẹ̀dẹ ṣe tí wọ́nkùn ní àwọ̀ aró àti eléṣé àlùkò,èyí jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ àwọn ọlọ́gbọ́n oníṣẹ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 10

Wo Jeremáyà 10:9 ni o tọ