Ṣùgbọ́n Olúwa ni Ọlọ́run tòótọ́,òun ni Ọlọ́run alààyè, Ọba ayérayé.Nígbà tí ó bá bínú, ayé yóò wárìrì;orílẹ̀ èdè kò lè fi ara da ìbínú rẹ̀.