Àwọn olùsọ́ àgùntàn jẹ́ aláìlóye, wọnkò sì wá Olúwa: nítorí náà wọn kì yóòṣe rere àti pé gbogbo agbo wọn ni yóò túká.