Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 10:19-21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

19. Ègbé ni fún mi nítorí ìpalára mi!Ọgbẹ́ mi jẹ́ èyí tí kò lè sàn, bẹ́ẹ̀ nimọ sọ fún ara mi,“Èyí ni àìsàn mi, mo sì gbọdọ̀ fi orí tì í.”

20. Àgọ́ mi bàjẹ́, gbogbo okùn rẹ̀ sì já.Àwọn ọmọ mi ti lọ lọ́dọ̀ mi, wọn kò sì sí mọ́Kò sí ẹnìkankan pẹ̀lú mi mọ́, báyìí kò sí ẹni tí yóòná àgọ́ mi tàbí ṣe ibùgbé fún mi

21. Àwọn olùsọ́ àgùntàn jẹ́ aláìlóye, wọnkò sì wá Olúwa: nítorí náà wọn kì yóòṣe rere àti pé gbogbo agbo wọn ni yóò túká.

Ka pipe ipin Jeremáyà 10