Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ògo Ọlọ́run sì gòkè kúrò lórí Kérúbù, níbi tó wà tẹ́lẹ̀ lọ síbi ìloro tẹ́ḿpìlì. Nígbà náà ni Olúwa pe ọkùnrin tó wọ aṣọ funfun lẹlẹ tí ó sì ní ohun ìkọ̀wé lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 9

Wo Ísíkẹ́lì 9:3 ni o tọ