Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 8:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, ṣé o ti rí ohun tí àwọn àgbààgbà ilé Ísírẹ́lì ń ṣe nínú òkùnkùn, olúkúlùkù ní yàrá òrìṣà rẹ̀? Wọ́n ní, ‘Olúwa kò rí wa; Olúwa ti kọ̀ ilé náà sílẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 8

Wo Ísíkẹ́lì 8:12 ni o tọ