Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwájú wọn ni àádọ́rin (70) ọkùnrin tó jẹ́ àgbà ilé Ísírẹ́lì dúró sí, Jáásáníà ọmọ Sáfánì sì dúró sáàrin wọn. Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì mú àwo tùràrí lọ́wọ́, òórùn sì ń tú jáde.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 8

Wo Ísíkẹ́lì 8:11 ni o tọ