Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 6:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wí pé: ‘Ẹ̀yin òkè Ísírẹ́lì, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa Ọlọ́run. Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí sí ẹ̀yin òkè ńlá àti àwọn òkè kékèké sí àwọn odò ṣíṣàn àti sí àfonífojì, n ó mú idà wa sórí yín, n ó sì pa ibi gíga yín run.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 6

Wo Ísíkẹ́lì 6:3 ni o tọ