Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìwà ìbọ̀rìṣà rẹ, n ó ṣe ohun tí n kò tí ì ṣe rí láàrin rẹ àti èyí tí n kò ní í ṣe irú rẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 5

Wo Ísíkẹ́lì 5:9 ni o tọ