Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 5:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà láàrin rẹ àwọn baba yóò má a jẹ ọmọ wọn, àwọn ọmọ náà yóò máa jẹ baba wọn. N ó jẹ ọ́ níyà, n ó sì tú àwọn tó bá ṣẹ́kù ká sínú èfúùfù.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 5

Wo Ísíkẹ́lì 5:10 ni o tọ