Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 5:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò rán ìyàn àti ẹranko búburú sí i yín, wọn yóò fi yín sílẹ ni àìlọ́mọ. Àjàkálẹ̀ àrùn àti ìtàjẹ̀-sílẹ̀ yóò kọjá láàrin yín. Èmi yóò si mú idà wá sórí rẹ. Èmi Olúwa ló sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 5

Wo Ísíkẹ́lì 5:17 ni o tọ