Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 48:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìwọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà tí a kọ sílẹ̀ pẹ̀lú orúkọ wọn: Ní òpin àríwá, Dánì yóò ni ìpín kan; èyí yóò tẹ̀lé ọ̀nà Hétílónù sí létí Hámátì; Hásárì Énánù àti ààlà àríwá tí Dámásíkù tí ó kángun sí Hámátì yóò jẹ́ ara ààlà rẹ̀ láti ìhà ìlà oòrùn títí lọ sí ìhà ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:1 ni o tọ