Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 46:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O sọ fún mi pé, “Èyí yìí ni ibi tí àwọn àlùfáà yóò ti ṣe ọrẹ ẹbọ ìdálẹ́bi àti ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àti tí wọn yóò ṣe ọrẹ ẹbọ jíjẹ, láti má se jẹ́ kí wọn mú wọn wá sí ìta àgbàlá kí wọn sì ya àwọn ènìyàn sí mímọ́.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 46

Wo Ísíkẹ́lì 46:20 ni o tọ