Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 46:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa Ọba wí Ẹnu ọ̀nà àgbàlá ti inú tí ó dojúkọ ìhà ìlà oòrùn ni kí a tì pa fún ọjọ́ mẹ́fà tí a fi ń ṣiṣẹ́, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ ìsinmí àti ní ọjọ́ oṣù tuntun ni kí a sí i.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 46

Wo Ísíkẹ́lì 46:1 ni o tọ