Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 45:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì pèsè éfà gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹbọ jíjẹ. Éfà kan fún akọ màlúù kọ̀ọ̀kan àti éfà kan fún àgbò kọ̀ọ̀kan, pẹ̀lú hini òróró kan fún éfà kan.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:24 ni o tọ