Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 45:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ojoojúmọ́ ni àárin ọjọ́ méje àṣè ni òun yóò pèsè akọ màlúù méje àti àgbò méje tí kò ní àbùkù gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹbọ sísun sí Olúwa, àti akọ ewúrẹ́ fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:23 ni o tọ