Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 45:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lára èyí, apákan ti ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ kọ̀ọ̀kan tí o jẹ́ ẹ̀ẹ́dégbẹ̀ta ìgbọ̀nwọ́ ní ó gbọdọ̀ wà fún ibi ìyàsímúmọ́ fún Ọlọ́run, pẹ̀lú ibẹ̀ tí ó jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́ fún ilẹ̀ tí ó yí ibi mímọ́ náà ká. Ilẹ̀ tí ó yí i ká yìí yóò wà bẹ́ẹ̀ láì lò ó.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:2 ni o tọ