Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 45:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nígbà ti ẹ̀yin bá pín ilẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ogún, ẹ gbọdọ̀ gbé ìpín ilẹ̀ kan kalẹ̀ fún Olúwa gẹ́gẹ́ bí agbègbè mímọ́, ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n ìgbọ̀nwọ́ ni gígùn àti ogún ẹgbẹ̀rún ìgbọ̀nwọ́ ni fífẹ̀; gbogbo agbègbè náà ni yóò jẹ́ mímọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:1 ni o tọ