Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 44:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà, ọkùnrin náà mú mi gba ẹnu ọ̀nà àríwá lọ sí iwájú ilé Ọlọ́run. Mo wò ó mo sì rí ògo Olúwa tí ó kún inú ilé Olúwa, mo sì dojúkọ ilẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:4 ni o tọ