Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 44:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ aládé fúnra rẹ̀ ní o lè jókòó ní ẹnu ọ̀nà náà kí o sì jẹun níwájú Olúwa. Ó gbọdọ̀ gba ọ̀nà ìlóro ẹnu ọ̀nà wọlé kí ó sì gba ibẹ̀ jáde.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:3 ni o tọ