Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 44:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Èmi ni kì ó jẹ́ ogún tí àwọn Àlùfáà yóò ní. Ẹ kò gbọdọ̀ fún wọn ni ìpín kankan ní Ísírẹ́lì; Èmi ni yóò jẹ́ ìpín wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:28 ni o tọ