Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 44:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Wọn kò gbọdọ̀ fá irun, wọn kò sì gbọdọ̀ jẹ́ kí irun wọn gùn, ṣùgbọ́n wọn gbọdọ̀ jẹ́ kí irun orí wọn wà ní gígẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 44

Wo Ísíkẹ́lì 44:20 ni o tọ