Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 41:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ẹnu ilẹ̀kùn ní ìta ibi mímọ́ ni àwọn kérúbù àti igi ọ̀pẹ tí a fín bí ti àwọn tí a fín si àwọn ara ògiri, ìbòrí tí á fí igi ṣe wà ní iwájú ẹnu ọ̀nà ilé ní ìta.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 41

Wo Ísíkẹ́lì 41:25 ni o tọ