Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́ḿpìlì mẹ́rin tí à fi òkúta ṣe lọ́sọ̀ọ́ sì tún wà fún ẹbọ sísun, ọ̀kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan àti ààbọ̀ ni gígùn, ìgbọ̀nwọ́ kan àti ààbọ̀ ní fífẹ̀ àti ìgbọ̀nwọ́ kan ni gíga. Ní orí rẹ̀ ni a kó àwọn ohun èlò fún pípa, ọrẹ ẹbọ sísun àti àwọn ìrubọ tí ó kù sí.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:42 ni o tọ