Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, tẹ́ḿpìlì mẹ́rin ni ó wà ní ẹ̀gbẹ́ kan ẹnu ọ̀nà, mẹ́rin sì wà ní ẹ̀gbẹ́ kejì tẹ́ḿpìlì, mẹ́jọ ni gbogbo rẹ̀ lórí èyí ni a ti ń pa ohun ìrúbọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:41 ni o tọ