Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà, o mú mi lọ sí ìhà gúsù, mo sì rí ẹnu ọ̀nà tí ó dojúkọ gúsù. Ó wọn àtẹ́rígbà àti àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà, wọ́n jẹ́ bákan náà bí ti àwọn tí o kù.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:24 ni o tọ