Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu ọ̀nà kan sí àgbàlá ti inú ni àdojúkọ ẹnu ọ̀nà àríwá, gẹ́gẹ́ bí o ṣe wà ní ìlà òòrùn. Ó wọ̀n láti ẹnu ọ̀nà sí àdojúkọ ọ̀kan; ó jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:23 ni o tọ