Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ìran Ọlọ́run, ó mú mí lọ sí ilẹ̀ Ísírẹ́lì, ó sì gbé mi lọ sí orí òkè gíga fíofío. Ní ẹ̀gbẹ́ gúsù ọ̀pọ̀ ilé tó wà níbẹ̀ dàbí ìlú ńlá.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:2 ni o tọ